Ṣaina - Wiktionary, the free dictionary
From Wiktionary, the free dictionary
![](https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/a/a4/CHN_orthographic.svg/220px-CHN_orthographic.svg.png)
Ṣáínà
- China (a country in eastern Asia)
2008, Lérè Adèyẹmí, Kò sáyè làáfin, page 2:
Bí wọn ti ń pè é ni Rọ́ṣíà ní wọn n bèèrè rẹ̀ ní Amẹ́ríkà, àwọn ìjọba Ṣáínà fé bá orílè̟-èdè Bóluwatife ṣe nítorí Ìwàlewà.
- (please add an English translation of this quotation)
2022 April 13, Eyitayọ Fauziat Oyetunji, “Shanghai pinnu láti fìyà jẹ ẹnikẹ́ni tó bá tàpá sófin ìgbélé ààrùn còrónà [Shanghai promises punishment for COVID-19 lockdown violators]”, in Ilé Akéde Nàìjíríà (Voice of Nigeria)[1], archived from the original on 16 January 2024:
Olú-ìlú ìṣòwò orílè-èdè Ṣáínà ní Shanghai ti kìlọ̀ pé ẹnikẹ́ni tí ó bá rú àwọn òfin ìgbélé ààrùn còrónà yóò jẹyán ẹ̀ níṣu.
- The Chinese commercial capital of Shanghai warned that anyone who violates COVID-19 lockdown rules will be dealt with strictly.