Potassium - Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́
- ️Tue Feb 28 2023
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Pòtásíọ̀mù je elimenti kemika kan to ni ami-idamo K (latinu ede Latini Tuntun fun kalium) ati nomba atomu 19. Potasiomu je metali alkali alawo fadaka-funfun didelowo to undi oksidi kiakia ninu afefe to si yirapo mo omi gigdigidi, eyi unfa igbona jade to sana si haidrojin to unbujade ninu iyirapo na, o si unjo bi awo lilaki.
Nitoripe potasiomu ati sodiomu jora ni isese kemika won, awon iyọ̀ won ko se e ya sira won nibere. O di odun 1702 ko to di pe won fun ra pe opo elimenti wa ninu awon iyo won,[4] eyi je mimufidaju ni odun 1807 nigba ti potasiomu ati sodiomu je yiya sotooto latinu awon iyọ̀ otooto pelu elektrolisisi. Potasiomu inu adaye wa ninu awon iyọ̀ oniioni nikan. Nitori eyi, o wa ninu omi okun (to je 0.04% potasiomu pelu iwuwo[5][6]), o si je apa opo awon alumoni.
- ↑ Meija, Juris; Coplen, Tyler B.; Berglund, Michael; Brand, Willi A.; De Bièvre, Paul; Gröning, Manfred; Holden, Norman E.; Irrgeher, Johanna et al. (2016). "Atomic weights of the elements 2013 (IUPAC Technical Report)". Pure and Applied Chemistry 88 (3): 265–91. doi:10.1515/pac-2015-0305.
- ↑ Àdàkọ:RubberBible92nd
- ↑ Magnetic susceptibility of the elements and inorganic compounds, in Àdàkọ:RubberBible86th
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named1702Suspect
- ↑ Webb, D. A. (April 1939). "The Sodium and Potassium Content of Sea Water". The Journal of Experimental Biology: 183. Archived from the original on 2023-02-28. https://web.archive.org/web/20230228192154/https://journals.biologists.com/jeb/article-pdf/16/2/178/2199202/jexbio_16_2_178.pdf. Retrieved 2023-03-02.
- ↑ Anthoni, J. (2006). "Detailed composition of seawater at 3.5% salinity". seafriends.org.nz. Retrieved 23 September 2011.
wò • if. • at. Tábìlì ìdásìkò | ||||||||||||||||||||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
1 | 2 | 3 | 4 | 5 | 6 | 7 | 8 | 9 | 10 | 11 | 12 | 13 | 14 | 15 | 16 | 17 | 18 | |||||||||||||||
1 | H | He | ||||||||||||||||||||||||||||||
2 | Li | Be | B | C | N | O | F | Ne | ||||||||||||||||||||||||
3 | Na | Mg | Al | Si | P | S | Cl | Ar | ||||||||||||||||||||||||
4 | K | Ca | Sc | Ti | V | Cr | Mn | Fe | Co | Ni | Cu | Zn | Ga | Ge | As | Se | Br | Kr | ||||||||||||||
5 | Rb | Sr | Y | Zr | Nb | Mo | Tc | Ru | Rh | Pd | Ag | Cd | In | Sn | Sb | Te | I | Xe | ||||||||||||||
6 | Cs | Ba | La | Ce | Pr | Nd | Pm | Sm | Eu | Gd | Tb | Dy | Ho | Er | Tm | Yb | Lu | Hf | Ta | W | Re | Os | Ir | Pt | Au | Hg | Tl | Pb | Bi | Po | At | Rn |
7 | Fr | Ra | Ac | Th | Pa | U | Np | Pu | Am | Cm | Bk | Cf | Es | Fm | Md | No | Lr | Rf | Db | Sg | Bh | Hs | Mt | Ds | Rg | Cn | Nh | Fl | Mc | Lv | Ts | Og |
| ||||||||||||||||||||||||||||||||